Search Header Logo

Yorùbá mid-test question Mary Ojo

Authored by GCL Schools

World Languages

1st - 5th Grade

Used 2+ times

Yorùbá mid-test question Mary Ojo
AI

AI Actions

Add similar questions

Adjust reading levels

Convert to real-world scenario

Translate activity

More...

    Content View

    Student View

12 questions

Show all answers

1.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

A ti kà ìwé ìtàn Yorùbá yìí nínú kíláàsì "Salewa ọmọ gidi"

Bẹẹni

Bẹẹkọ

Èmi kò mọ

2.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Ọmọ ọdún mélòó ni àwọn àbúrò Salewa

Mẹrin

Márùn-ún

Meji

Meesan

3.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Akanbi kọ́ gbogbo àwọn ẹ̀kọ́ yìí nínú kíláàsì, ayafi

Alifabeeti Yorùbá

Ìkíni ni èdè Yorùbá

Àwọn oúnjẹ ilé wa

Akanlo èdè

4.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Kini ìdí tí a fi ń pe Salewa ni ọmọ gidi

O má ń jà pẹ̀lú àwọn ọ̀rẹ́ rẹ

O má ń sunkún

O má ń ka ìwé

O má ń sùn

5.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Salewa ká àwọn ìwé yìí yàtò sì èwo

Ìwé lórí èdè igbo

Ìwé lórí èdè Faransé

Ìwé lórí èdè Yorùbá

6.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Èdè mélòó ni Salewa lè sọ?

Mesan

Meewa

Mẹta

Meji

7.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Kini olu-ilu orileede Kenya

Cuba

Niger

Nairobi

Nigeria

Access all questions and much more by creating a free account

Create resources

Host any resource

Get auto-graded reports

Google

Continue with Google

Email

Continue with Email

Microsoft

Continue with Microsoft

or continue with

Facebook

Facebook

Apple

Apple

Others

Others

Already have an account?