
Short Story -- Alọ Kukuru
Presentation
•
World Languages
•
1st Grade - Professional Development
•
Hard
Morufat Adeniran
Used 5+ times
FREE Resource
3 Slides • 0 Questions
1
Kini a ma kọ?:
A ma kọ bi a n ṣe sọ oriṣiriṣi ounjẹ ni ede Yoruba.
A ma kọ awọn nnkan ati ọrọ ti o lọ pẹlu ounjẹ sise tabi jijẹ ni ede Yoruba.
Ounjẹ ni gbogbo nkan ti a ma n fi si ẹnu ti ko ni jẹ ki ebi pa wa, ti o si n ma n fun ara ni alaafia.
Akọle Alọ:
Ounjẹ mi
2
Ni owurọ ọjọ kan, Anikẹ ji, o joko si ori ibusun bi ikun ẹ ṣe pariwo. O ranti pe oun ko jẹun ni ale ana.
O dide lọ si yara ẹgbọn rẹ. Ige ti wẹ, o n wọ aṣo re. 'E kaarọ boda mi. 'Anikẹ ki egbọn rẹ. 'Ṣe daada ni o ji, Anike mi ọwọn' ẹgbọn re dahun.
Anikẹ sọ fun ẹgbọn rẹ pe ebi n pa oun. Ige r'ẹrin, o sọ fun pe oun mọ pe ebi ni a ji nitori pe ko jẹun ki o to lọ sun.
Awọn mejeji jade kuro ninu yara lọ si ile idana. Anikẹ ni Iṣu, ẹyin ati obe ẹja dindin ni oun fẹran ju sugbọn oun ma jẹ ẹwa ati dodo ti oun o jẹ ni ana ki o ba ya.
Kini ounjẹ ti Anike fẹran ju? Ounje wo ni Anike wa jẹ? Kini idi ti o fi je ounjẹ mi yato si'yi ti o fẹran ju? Ti iwọ ba jẹ Anikẹ, ounjẹ wo ni wa jẹ ati pe kini idi naa?
3
One early morning, Anikẹ woke up, she sat up on the bed as her tummy rumbled. She remembered that she did not eat last night.
She got up and went to her brother's room.Ige had taken a bath and was wearing his clothes. 'Good morning my brother. 'Anikẹ greeted her older brother. 'Did you sleep well, my dear Anike' her older brother responsed.
Anikẹ told him that she was hungry. Ige laughed and told her that he knew she was going to wake up very hungry because she did not eat before going to bed.
They went out of the room to the kitchen. Anikẹ said her favourite food was yam and egg with fish stew but she would the eat beans and fried plantain she did not eat last night so it can be fast.
What is Anikẹ's favourite food? Which food did she eat? Why did she eat something different from her favourite food? If you were Anikẹ, which food would you eat and why? Tell me about your favourite food?
Kini a ma kọ?:
A ma kọ bi a n ṣe sọ oriṣiriṣi ounjẹ ni ede Yoruba.
A ma kọ awọn nnkan ati ọrọ ti o lọ pẹlu ounjẹ sise tabi jijẹ ni ede Yoruba.
Ounjẹ ni gbogbo nkan ti a ma n fi si ẹnu ti ko ni jẹ ki ebi pa wa, ti o si n ma n fun ara ni alaafia.
Akọle Alọ:
Ounjẹ mi
Show answer
Auto Play
Slide 1 / 3
SLIDE
Similar Resources on Wayground
5 questions
Lengua y Literatura
Presentation
•
KG
5 questions
tecnologia como usarla
Presentation
•
1st Grade - Professio...
8 questions
MOISÉS Y LA ZARZA ARDIENTE
Presentation
•
KG
10 questions
LEARN ITALIAN
Presentation
•
KG - Professional Dev...
9 questions
Positive Psychology
Presentation
•
KG - Professional Dev...
6 questions
Untitled Presentation
Presentation
•
KG
4 questions
los sustantivos
Presentation
•
KG - University
Popular Resources on Wayground
10 questions
Safety Day 2026 – Student Review
Quiz
•
9th Grade
21 questions
Continents and Oceans
Quiz
•
6th Grade
20 questions
Parts of Speech
Quiz
•
5th Grade
16 questions
Subject & Predicate
Quiz
•
5th Grade
25 questions
Multiplication Facts
Quiz
•
5th Grade
12 questions
Map Skills
Quiz
•
3rd Grade
22 questions
Continents and Oceans
Quiz
•
5th Grade
15 questions
Rounding Decimals
Quiz
•
5th Grade
Discover more resources for World Languages
20 questions
REGULAR Present tense verbs
Quiz
•
8th - 9th Grade
21 questions
Los paises hispanohablantes y sus capitales
Quiz
•
12th Grade
20 questions
Ser vs Estar
Quiz
•
9th Grade
21 questions
Spanish speaking countries and capitals
Quiz
•
9th Grade
20 questions
Preterite vs. Imperfect
Quiz
•
10th Grade
20 questions
Present tense stem-changing verbs
Quiz
•
9th Grade
14 questions
Los Dias de la Semana
Quiz
•
6th - 8th Grade
20 questions
Ser vs. Estar
Quiz
•
10th Grade